2 Tímótì 1:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Torí náà, má ṣe tijú láti jẹ́rìí nípa Olúwa wa+ tàbí èmi, ẹlẹ́wọ̀n nítorí rẹ̀, àmọ́ kí ìwọ náà jìyà torí ìhìn rere,+ kí o sì gbára lé agbára Ọlọ́run.+
8 Torí náà, má ṣe tijú láti jẹ́rìí nípa Olúwa wa+ tàbí èmi, ẹlẹ́wọ̀n nítorí rẹ̀, àmọ́ kí ìwọ náà jìyà torí ìhìn rere,+ kí o sì gbára lé agbára Ọlọ́run.+