1 Tímótì 1:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Tímótì ọmọ mi, mo fi ìtọ́ni* yìí sí ìkáwọ́ rẹ, ní ìbámu pẹ̀lú àwọn nǹkan tí a sọ tẹ́lẹ̀ nípa rẹ, pé kí o lè máa fi wọ́n ja ogun rere,+
18 Tímótì ọmọ mi, mo fi ìtọ́ni* yìí sí ìkáwọ́ rẹ, ní ìbámu pẹ̀lú àwọn nǹkan tí a sọ tẹ́lẹ̀ nípa rẹ, pé kí o lè máa fi wọ́n ja ogun rere,+