2 Kọ́ríńtì 1:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Nígbà náà, tí a bá dojú kọ àdánwò,* torí ìtùnú àti ìgbàlà yín ni; tí a bá sì ń tù wá nínú, torí kí ẹ lè rí ìtùnú ni, èyí tó máa jẹ́ kí ẹ lè fara da ìyà kan náà tí à ń jẹ. Éfésù 3:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Nítorí náà, mo sọ fún yín pé kí ẹ má juwọ́ sílẹ̀ nítorí àwọn ìpọ́njú tí mo ní lórí yín, torí wọ́n ń yọrí sí ògo fún yín.+ Kólósè 1:24 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 24 Ní báyìí, mò ń yọ̀ nínú ìyà tí mò ń jẹ lórí yín,+ mo sì ń ní ìpọ́njú Kristi tí mi ò tíì ní nínú ẹran ara mi nítorí ara rẹ̀,+ ìyẹn ìjọ.+
6 Nígbà náà, tí a bá dojú kọ àdánwò,* torí ìtùnú àti ìgbàlà yín ni; tí a bá sì ń tù wá nínú, torí kí ẹ lè rí ìtùnú ni, èyí tó máa jẹ́ kí ẹ lè fara da ìyà kan náà tí à ń jẹ.
13 Nítorí náà, mo sọ fún yín pé kí ẹ má juwọ́ sílẹ̀ nítorí àwọn ìpọ́njú tí mo ní lórí yín, torí wọ́n ń yọrí sí ògo fún yín.+
24 Ní báyìí, mò ń yọ̀ nínú ìyà tí mò ń jẹ lórí yín,+ mo sì ń ní ìpọ́njú Kristi tí mi ò tíì ní nínú ẹran ara mi nítorí ara rẹ̀,+ ìyẹn ìjọ.+