Róòmù 8:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Torí kì í ṣe ẹ̀mí ìsìnrú tó ń múni pa dà sínú ìbẹ̀rù lẹ gbà, ẹ̀mí ìsọdọmọ lẹ gbà, ẹ̀mí tó ń mú ká ké jáde pé: “Ábà,* Bàbá!”+ 1 Tẹsalóníkà 2:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Nítorí bó tilẹ̀ jẹ́ pé a ti kọ́kọ́ jìyà, tí wọ́n sì hùwà àfojúdi sí wa ní ìlú Fílípì,+ bí ẹ̀yin náà ṣe mọ̀, Ọlọ́run wa mú kí a mọ́kàn le* kí a lè sọ ìhìn rere Ọlọ́run+ fún yín lójú ọ̀pọ̀ àtakò.*
15 Torí kì í ṣe ẹ̀mí ìsìnrú tó ń múni pa dà sínú ìbẹ̀rù lẹ gbà, ẹ̀mí ìsọdọmọ lẹ gbà, ẹ̀mí tó ń mú ká ké jáde pé: “Ábà,* Bàbá!”+
2 Nítorí bó tilẹ̀ jẹ́ pé a ti kọ́kọ́ jìyà, tí wọ́n sì hùwà àfojúdi sí wa ní ìlú Fílípì,+ bí ẹ̀yin náà ṣe mọ̀, Ọlọ́run wa mú kí a mọ́kàn le* kí a lè sọ ìhìn rere Ọlọ́run+ fún yín lójú ọ̀pọ̀ àtakò.*