1 Kọ́ríńtì 15:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Ní báyìí, tí a bá ń wàásù pé a ti gbé Kristi dìde kúrò nínú ikú,+ kí nìdí tí àwọn kan láàárín yín fi ń sọ pé kò sí àjíǹde àwọn òkú?
12 Ní báyìí, tí a bá ń wàásù pé a ti gbé Kristi dìde kúrò nínú ikú,+ kí nìdí tí àwọn kan láàárín yín fi ń sọ pé kò sí àjíǹde àwọn òkú?