Jòhánù 13:27 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 27 Lẹ́yìn tí Júdásì gba búrẹ́dì náà, Sátánì wọ inú Júdásì.+ Torí náà, Jésù sọ fún un pé: “Tètè ṣe ohun tí ò ń ṣe kíákíá.” Ìṣe 5:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Àmọ́ Pétérù sọ pé: “Ananáyà, kí ló dé tí Sátánì fi kì ọ́ láyà láti parọ́ + fún ẹ̀mí mímọ́,+ tí o fi yọ lára owó ilẹ̀ náà pa mọ́? 1 Tímótì 1:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Híméníọ́sì+ àti Alẹkisáńdà wà lára irú àwọn èèyàn bẹ́ẹ̀, mo sì ti fi wọ́n lé Sátánì lọ́wọ́,+ kí a lè fi ìbáwí kọ́ wọn lẹ́kọ̀ọ́ pé kí wọ́n má sọ̀rọ̀ òdì mọ́.
27 Lẹ́yìn tí Júdásì gba búrẹ́dì náà, Sátánì wọ inú Júdásì.+ Torí náà, Jésù sọ fún un pé: “Tètè ṣe ohun tí ò ń ṣe kíákíá.”
3 Àmọ́ Pétérù sọ pé: “Ananáyà, kí ló dé tí Sátánì fi kì ọ́ láyà láti parọ́ + fún ẹ̀mí mímọ́,+ tí o fi yọ lára owó ilẹ̀ náà pa mọ́?
20 Híméníọ́sì+ àti Alẹkisáńdà wà lára irú àwọn èèyàn bẹ́ẹ̀, mo sì ti fi wọ́n lé Sátánì lọ́wọ́,+ kí a lè fi ìbáwí kọ́ wọn lẹ́kọ̀ọ́ pé kí wọ́n má sọ̀rọ̀ òdì mọ́.