Mátíù 7:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 “Ẹ máa ṣọ́ra fún àwọn wòlíì èké+ tó ń wá sọ́dọ̀ yín nínú àwọ̀ àgùntàn,+ àmọ́ tó jẹ́ pé ọ̀yánnú ìkookò ni wọ́n ní inú.+ Mátíù 7:22, 23 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Ọ̀pọ̀ máa sọ fún mi ní ọjọ́ yẹn pé: ‘Olúwa, Olúwa,+ ṣebí a fi orúkọ rẹ sọ tẹ́lẹ̀, a fi orúkọ rẹ lé àwọn ẹ̀mí èṣù jáde, a sì fi orúkọ rẹ ṣe ọ̀pọ̀ iṣẹ́ agbára?’+ 23 Àmọ́, màá sọ fún wọn pé: ‘Mi ò mọ̀ yín rí! Ẹ kúrò lọ́dọ̀ mi, ẹ̀yin arúfin!’+
15 “Ẹ máa ṣọ́ra fún àwọn wòlíì èké+ tó ń wá sọ́dọ̀ yín nínú àwọ̀ àgùntàn,+ àmọ́ tó jẹ́ pé ọ̀yánnú ìkookò ni wọ́n ní inú.+
22 Ọ̀pọ̀ máa sọ fún mi ní ọjọ́ yẹn pé: ‘Olúwa, Olúwa,+ ṣebí a fi orúkọ rẹ sọ tẹ́lẹ̀, a fi orúkọ rẹ lé àwọn ẹ̀mí èṣù jáde, a sì fi orúkọ rẹ ṣe ọ̀pọ̀ iṣẹ́ agbára?’+ 23 Àmọ́, màá sọ fún wọn pé: ‘Mi ò mọ̀ yín rí! Ẹ kúrò lọ́dọ̀ mi, ẹ̀yin arúfin!’+