Ìṣe 13:50 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 50 Àmọ́ àwọn Júù ru àwọn obìnrin olókìkí tó bẹ̀rù Ọlọ́run àti àwọn ọkùnrin sàràkí-sàràkí ìlú náà sókè, wọ́n gbé inúnibíni+ dìde sí Pọ́ọ̀lù àti Bánábà, wọ́n sì jù wọ́n sí ẹ̀yìn ààlà ìlú wọn.
50 Àmọ́ àwọn Júù ru àwọn obìnrin olókìkí tó bẹ̀rù Ọlọ́run àti àwọn ọkùnrin sàràkí-sàràkí ìlú náà sókè, wọ́n gbé inúnibíni+ dìde sí Pọ́ọ̀lù àti Bánábà, wọ́n sì jù wọ́n sí ẹ̀yìn ààlà ìlú wọn.