Jòhánù 5:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Torí Baba kì í ṣèdájọ́ ẹnikẹ́ni, àmọ́ ó ti fi gbogbo ìdájọ́ lé Ọmọ lọ́wọ́,+