Éfésù 1:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 bí ó ṣe yàn wá láti wà ní ìṣọ̀kan pẹ̀lú rẹ̀* ṣáájú ìgbà pípilẹ̀ ayé, kí a lè jẹ́ mímọ́, kí a sì wà láìní àbààwọ́n+ níwájú rẹ̀ nínú ìfẹ́. Hébérù 3:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Torí náà, ẹ̀yin ará tí ẹ jẹ́ mímọ́, ẹ̀yin tí ẹ ní ìpè* ti ọ̀run,+ ẹ ronú nípa àpọ́sítélì àti àlùfáà àgbà tí a gbà,* ìyẹn Jésù.+
4 bí ó ṣe yàn wá láti wà ní ìṣọ̀kan pẹ̀lú rẹ̀* ṣáájú ìgbà pípilẹ̀ ayé, kí a lè jẹ́ mímọ́, kí a sì wà láìní àbààwọ́n+ níwájú rẹ̀ nínú ìfẹ́.
3 Torí náà, ẹ̀yin ará tí ẹ jẹ́ mímọ́, ẹ̀yin tí ẹ ní ìpè* ti ọ̀run,+ ẹ ronú nípa àpọ́sítélì àti àlùfáà àgbà tí a gbà,* ìyẹn Jésù.+