Ìṣe 19:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Torí náà, ó rán Tímótì+ àti Érásítù,+ méjì lára àwọn tó ń ṣe ìránṣẹ́ fún un, lọ sí Makedóníà, àmọ́ òun fúnra rẹ̀ lo àkókò díẹ̀ sí i ní ìpínlẹ̀ Éṣíà.
22 Torí náà, ó rán Tímótì+ àti Érásítù,+ méjì lára àwọn tó ń ṣe ìránṣẹ́ fún un, lọ sí Makedóníà, àmọ́ òun fúnra rẹ̀ lo àkókò díẹ̀ sí i ní ìpínlẹ̀ Éṣíà.