-
1 Tímótì 6:2Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
2 Bákan náà, kí àwọn tí olúwa wọn jẹ́ onígbàgbọ́ má ṣe hùwà àìlọ́wọ̀ sí wọn torí wọ́n jẹ́ ará. Kàkà bẹ́ẹ̀, kí wọ́n túbọ̀ máa ṣe ìránṣẹ́, torí àwọn tó ń jàǹfààní iṣẹ́ ìsìn rere wọn jẹ́ onígbàgbọ́ àti àyànfẹ́.
Túbọ̀ máa fi nǹkan wọ̀nyí kọ́ni, kí o sì máa gbani níyànjú.
-