Róòmù 16:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Bákan náà, ẹ kí ìjọ tó wà ní ilé wọn.+ Ẹ kí Épénétù àyànfẹ́ mi, tó jẹ́ àkọ́so ní Éṣíà fún Kristi. 1 Kọ́ríńtì 16:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Àwọn ìjọ tó wà ní Éṣíà kí yín. Ákúílà àti Pírísíkà pẹ̀lú ìjọ tó wà ní ilé wọn+ kí yín tayọ̀tayọ̀ nínú Olúwa.
19 Àwọn ìjọ tó wà ní Éṣíà kí yín. Ákúílà àti Pírísíkà pẹ̀lú ìjọ tó wà ní ilé wọn+ kí yín tayọ̀tayọ̀ nínú Olúwa.