1 Kọ́ríńtì 4:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Nítorí bí ẹ bá tiẹ̀ ní ẹgbẹ̀rún mẹ́wàá (10,000) atọ́nisọ́nà* nínú Kristi, ẹ kò ní baba púpọ̀; torí nínú Kristi Jésù, mo di baba yín nípasẹ̀ ìhìn rere.+
15 Nítorí bí ẹ bá tiẹ̀ ní ẹgbẹ̀rún mẹ́wàá (10,000) atọ́nisọ́nà* nínú Kristi, ẹ kò ní baba púpọ̀; torí nínú Kristi Jésù, mo di baba yín nípasẹ̀ ìhìn rere.+