Sáàmù 2:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Ẹ jẹ́ kí n kéde àṣẹ Jèhófà;Ó sọ fún mi pé: “Ìwọ ni ọmọ mi;+Òní ni mo di bàbá rẹ.+