Hébérù 10:32, 33 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 32 Àmọ́, ẹ máa rántí àwọn ọjọ́ àtijọ́, tí ẹ fara da ìjàkadì ńlá pẹ̀lú ìyà, lẹ́yìn tí a là yín lóye.+ 33 Nígbà míì, wọ́n máa ń tú yín síta gbangba* fún ẹ̀gàn àti ìpọ́njú, nígbà míì sì rèé, ẹ máa ń ṣe alábàápín pẹ̀lú* àwọn tí irú nǹkan bẹ́ẹ̀ ṣẹlẹ̀ sí.
32 Àmọ́, ẹ máa rántí àwọn ọjọ́ àtijọ́, tí ẹ fara da ìjàkadì ńlá pẹ̀lú ìyà, lẹ́yìn tí a là yín lóye.+ 33 Nígbà míì, wọ́n máa ń tú yín síta gbangba* fún ẹ̀gàn àti ìpọ́njú, nígbà míì sì rèé, ẹ máa ń ṣe alábàápín pẹ̀lú* àwọn tí irú nǹkan bẹ́ẹ̀ ṣẹlẹ̀ sí.