Jòhánù 1:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Torí náà, Ọ̀rọ̀ náà di ẹlẹ́ran ara,+ ó gbé láàárín wa, a sì rí ògo rẹ̀, irú ògo tó jẹ́ ti ọmọ bíbí kan ṣoṣo+ ti bàbá kan; ó sì kún fún oore Ọlọ́run* àti òtítọ́. Róòmù 8:29 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 29 nítorí àwọn tó kọ́kọ́ fún ní àfiyèsí ló tún yàn ṣáájú láti jẹ́ àwòrán Ọmọ rẹ̀,+ kó lè jẹ́ àkọ́bí+ láàárín ọ̀pọ̀ arákùnrin.+ Kólósè 1:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Òun ni àwòrán Ọlọ́run tí a kò lè rí,+ àkọ́bí nínú gbogbo ẹ̀dá; +
14 Torí náà, Ọ̀rọ̀ náà di ẹlẹ́ran ara,+ ó gbé láàárín wa, a sì rí ògo rẹ̀, irú ògo tó jẹ́ ti ọmọ bíbí kan ṣoṣo+ ti bàbá kan; ó sì kún fún oore Ọlọ́run* àti òtítọ́.
29 nítorí àwọn tó kọ́kọ́ fún ní àfiyèsí ló tún yàn ṣáájú láti jẹ́ àwòrán Ọmọ rẹ̀,+ kó lè jẹ́ àkọ́bí+ láàárín ọ̀pọ̀ arákùnrin.+