Éfésù 5:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 kí ẹ sì máa rìn nínú ìfẹ́,+ bí Kristi pẹ̀lú ṣe nífẹ̀ẹ́ wa,*+ tó sì fi ara rẹ̀ lélẹ̀ fún wa* bí ọrẹ àti ẹbọ, tó jẹ́ òórùn dídùn sí Ọlọ́run.+
2 kí ẹ sì máa rìn nínú ìfẹ́,+ bí Kristi pẹ̀lú ṣe nífẹ̀ẹ́ wa,*+ tó sì fi ara rẹ̀ lélẹ̀ fún wa* bí ọrẹ àti ẹbọ, tó jẹ́ òórùn dídùn sí Ọlọ́run.+