6 ní tiwa, Ọlọ́run kan ṣoṣo ló wà,+ Baba,+ ọ̀dọ̀ ẹni tí ohun gbogbo ti wá, tí àwa náà sì wà fún un;+ Olúwa kan ló wà, Jésù Kristi, ipasẹ̀ ẹni tí ohun gbogbo fi wà,+ tí àwa náà sì wà nípasẹ̀ rẹ̀.
16 nítorí ipasẹ̀ rẹ̀ ni a dá gbogbo ohun mìíràn ní ọ̀run àti ní ayé, àwọn ohun tí a lè rí àti àwọn ohun tí a kò lè rí,+ ì báà jẹ́ ìtẹ́ tàbí ipò olúwa tàbí ìjọba tàbí àṣẹ. Gbogbo ohun mìíràn ni a dá nípasẹ̀ rẹ̀+ àti nítorí rẹ̀.