Jòhánù 1:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Torí náà, Ọ̀rọ̀ náà di ẹlẹ́ran ara,+ ó gbé láàárín wa, a sì rí ògo rẹ̀, irú ògo tó jẹ́ ti ọmọ bíbí kan ṣoṣo+ ti bàbá kan; ó sì kún fún oore Ọlọ́run* àti òtítọ́. Jòhánù 17:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Torí náà, ní báyìí, Baba, ṣe mí lógo lẹ́gbẹ̀ẹ́ rẹ pẹ̀lú ògo tí mo ti ní lẹ́gbẹ̀ẹ́ rẹ kí ayé tó wà.+
14 Torí náà, Ọ̀rọ̀ náà di ẹlẹ́ran ara,+ ó gbé láàárín wa, a sì rí ògo rẹ̀, irú ògo tó jẹ́ ti ọmọ bíbí kan ṣoṣo+ ti bàbá kan; ó sì kún fún oore Ọlọ́run* àti òtítọ́.
5 Torí náà, ní báyìí, Baba, ṣe mí lógo lẹ́gbẹ̀ẹ́ rẹ pẹ̀lú ògo tí mo ti ní lẹ́gbẹ̀ẹ́ rẹ kí ayé tó wà.+