Ìsíkíẹ́lì 7:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 “‘Wọ́n á ju fàdákà wọn sí ojú ọ̀nà, wúrà wọn á sì di ohun ìríra lójú wọn. Fàdákà wọn tàbí wúrà wọn kò ní lè gbà wọ́n là ní ọjọ́ ìbínú Jèhófà.+ Kò ní tẹ́ wọn* lọ́rùn, wọn ò sì ní yó, torí ó* ti di ohun ìkọ̀sẹ̀ tó ń mú kí wọ́n ṣe àṣìṣe.
19 “‘Wọ́n á ju fàdákà wọn sí ojú ọ̀nà, wúrà wọn á sì di ohun ìríra lójú wọn. Fàdákà wọn tàbí wúrà wọn kò ní lè gbà wọ́n là ní ọjọ́ ìbínú Jèhófà.+ Kò ní tẹ́ wọn* lọ́rùn, wọn ò sì ní yó, torí ó* ti di ohun ìkọ̀sẹ̀ tó ń mú kí wọ́n ṣe àṣìṣe.