Jòhánù 15:26, 27 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 26 Nígbà tí olùrànlọ́wọ́ tí màá rán sí yín látọ̀dọ̀ Baba bá dé, ẹ̀mí òtítọ́,+ tó wá látọ̀dọ̀ Baba, ó máa jẹ́rìí nípa mi;+ 27 kí ẹ̀yin náà sì jẹ́rìí,+ torí pé ẹ ti wà pẹ̀lú mi láti ìbẹ̀rẹ̀. Ìṣe 4:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Àmọ́ ní tiwa, a ò lè ṣàì sọ ohun tí a ti rí tí a sì ti gbọ́.”+
26 Nígbà tí olùrànlọ́wọ́ tí màá rán sí yín látọ̀dọ̀ Baba bá dé, ẹ̀mí òtítọ́,+ tó wá látọ̀dọ̀ Baba, ó máa jẹ́rìí nípa mi;+ 27 kí ẹ̀yin náà sì jẹ́rìí,+ torí pé ẹ ti wà pẹ̀lú mi láti ìbẹ̀rẹ̀.