ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Ìṣe 15:25
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 25 a ti fìmọ̀ ṣọ̀kan, a sì ti pinnu láti yan àwọn ọkùnrin tí a máa rán sí yín pẹ̀lú àwọn àyànfẹ́ wa, Bánábà àti Pọ́ọ̀lù,

  • Ìṣe 15:27
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 27 Nítorí náà, à ń rán Júdásì àti Sílà bọ̀, kí àwọn náà lè fi ọ̀rọ̀ ẹnu jíṣẹ́ + ohun kan náà fún yín.

  • Éfésù 6:21
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 21 Kí ẹ lè mọ̀ nípa mi àti bí mo ṣe ń ṣe sí, Tíkíkù,+ arákùnrin ọ̀wọ́n, tó tún jẹ́ òjíṣẹ́ olóòótọ́ nínú Olúwa, yóò sọ gbogbo rẹ̀ fún yín.+

  • Fílípì 2:19
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 19 Ní báyìí, mo ní ìrètí pé, tí Jésù Olúwa bá fẹ́, màá rán Tímótì+ sí yín láìpẹ́, kí ara mi lè yá gágá nígbà tí mo bá gbọ́ ìròyìn nípa yín.

  • Kólósè 4:7
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 7 Tíkíkù,+ arákùnrin mi ọ̀wọ́n tó jẹ́ òjíṣẹ́ olóòótọ́ àti ẹrú ẹlẹgbẹ́ mi nínú Olúwa, máa ròyìn gbogbo ohun tó ṣẹlẹ̀ sí mi fún yín.

  • Títù 1:5
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 5 Mo fi ọ́ sílẹ̀ ní Kírétè, kí o lè ṣe àtúnṣe àwọn ohun tí kò tọ́,* kí o sì lè yan àwọn alàgbà láti ìlú dé ìlú, bí mo ṣe sọ fún ọ pé kí o ṣe:

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́