Róòmù 12:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Ẹ jẹ́ kí ìfẹ́ yín wà láìsí ẹ̀tàn.*+ Ẹ kórìíra ohun búburú;+ ẹ rọ̀ mọ́ ohun rere. 1 Pétérù 3:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Kí ó jáwọ́ nínú ohun búburú,+ kó sì máa ṣe rere;+ kó máa wá àlàáfíà, kó sì máa lépa rẹ̀.+