Títù 3:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Tún rí i pé o fún Sénásì, ẹni tó mọ Òfin dunjú àti Àpólò ní ohun tí wọ́n nílò kí wọ́n má bàa ṣaláìní ohunkóhun lẹ́nu ìrìn àjò wọn.+
13 Tún rí i pé o fún Sénásì, ẹni tó mọ Òfin dunjú àti Àpólò ní ohun tí wọ́n nílò kí wọ́n má bàa ṣaláìní ohunkóhun lẹ́nu ìrìn àjò wọn.+