Ìṣe 20:29, 30 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 29 Mo mọ̀ pé lẹ́yìn tí mo bá lọ, àwọn aninilára ìkookò máa wọlé sáàárín yín,+ wọn ò sì ní fọwọ́ pẹ̀lẹ́ mú agbo, 30 àwọn kan máa dìde láàárín yín, wọ́n á sọ àwọn ọ̀rọ̀ békebèke láti fa àwọn ọmọ ẹ̀yìn sẹ́yìn ara wọn.+
29 Mo mọ̀ pé lẹ́yìn tí mo bá lọ, àwọn aninilára ìkookò máa wọlé sáàárín yín,+ wọn ò sì ní fọwọ́ pẹ̀lẹ́ mú agbo, 30 àwọn kan máa dìde láàárín yín, wọ́n á sọ àwọn ọ̀rọ̀ békebèke láti fa àwọn ọmọ ẹ̀yìn sẹ́yìn ara wọn.+