Sáàmù 1:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Ṣùgbọ́n òfin Jèhófà máa ń mú inú rẹ̀ dùn,+Ó sì ń fi ohùn jẹ́ẹ́jẹ́ẹ́ ka* òfin Rẹ̀ tọ̀sántòru.+ Lúùkù 11:28 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 28 Àmọ́ ó sọ pé: “Rárá o, kàkà bẹ́ẹ̀, aláyọ̀ ni àwọn tó ń gbọ́ ọ̀rọ̀ Ọlọ́run, tí wọ́n sì ń pa á mọ́!”+ Jòhánù 13:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Tí ẹ bá mọ àwọn nǹkan yìí, aláyọ̀ ni yín tí ẹ bá ń ṣe wọ́n.+ Jémíìsì 1:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Àmọ́, ẹ máa ṣe ohun tí ọ̀rọ̀ náà sọ,+ ẹ má kàn máa gbọ́ ọ lásán, kí ẹ wá máa fi èrò èké tan ara yín jẹ.
28 Àmọ́ ó sọ pé: “Rárá o, kàkà bẹ́ẹ̀, aláyọ̀ ni àwọn tó ń gbọ́ ọ̀rọ̀ Ọlọ́run, tí wọ́n sì ń pa á mọ́!”+
22 Àmọ́, ẹ máa ṣe ohun tí ọ̀rọ̀ náà sọ,+ ẹ má kàn máa gbọ́ ọ lásán, kí ẹ wá máa fi èrò èké tan ara yín jẹ.