Ìfihàn 13:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Ibi tó ti gba ọgbọ́n nìyí: Kí ẹni tó ní òye ṣírò nọ́ńbà ẹranko náà, torí pé nọ́ńbà èèyàn ni,* nọ́ńbà rẹ̀ sì ni ọgọ́rùn-ún mẹ́fà àti ọgọ́ta ó lé mẹ́fà (666).+
18 Ibi tó ti gba ọgbọ́n nìyí: Kí ẹni tó ní òye ṣírò nọ́ńbà ẹranko náà, torí pé nọ́ńbà èèyàn ni,* nọ́ńbà rẹ̀ sì ni ọgọ́rùn-ún mẹ́fà àti ọgọ́ta ó lé mẹ́fà (666).+