Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun Ohun Tó Wà Nínú Ìwé 2 Àwọn Ọba 2 ÀWỌN ỌBA OHUN TÓ WÀ NÍNÚ ÌWÉ YÌÍ 1 Èlíjà sọ tẹ́lẹ̀ pé Ahasáyà máa kú (1-18) 2 Ọlọ́run fi ìjì gbé Èlíjà lọ sókè (1-18) Èlíṣà rí ẹ̀wù Èlíjà gbà (13, 14) Èlíṣà wo omi Jẹ́ríkò sàn (19-22) Àwọn bíárì pa àwọn ọmọdékùnrin tó jáde wá láti Bẹ́tẹ́lì (23-25) 3 Jèhórámù di ọba Ísírẹ́lì (1-3) Móábù ṣọ̀tẹ̀ sí Ísírẹ́lì (4-25) Wọ́n ṣẹ́gun Móábù (26, 27) 4 Èlíṣà sọ òróró opó kan di púpọ̀ (1-7) Obìnrin ará Ṣúnémù ṣe àlejò (8-16) Obìnrin kan rí ọmọ bí; ọmọ náà kú (17-31) Èlíṣà jí ọmọ tó kú dìde (32-37) Èlíṣà mú kí ọbẹ̀ kan ṣeé jẹ (38-41) Èlíṣà sọ búrẹ́dì di púpọ̀ (42-44) 5 Èlíṣà wo ẹ̀tẹ̀ Náámánì sàn (1-19) Ẹ̀tẹ̀ kọ lu Géhásì olójúkòkòrò (20-27) 6 Èlíṣà mú kí irin àáké léfòó (1-7) Èlíṣà àti àwọn ará Síríà (8-23) Ojú ìránṣẹ́ Èlíṣà là (16, 17) Ojú inú àwọn ará Síríà fọ́ (18, 19) Ìyàn mú ní Samáríà nígbà tí wọ́n dó tì í (24-33) 7 Èlíṣà sọ tẹ́lẹ̀ pé ìyàn máa dópin (1, 2) Wọ́n rí oúnjẹ ní ibùdó tí àwọn ará Síríà ti sá kúrò (3-15) Àsọtẹ́lẹ̀ Èlíṣà ṣẹ (16-20) 8 Wọ́n dá ilẹ̀ obìnrin ará Ṣúnémù pa dà fún un (1-6) Èlíṣà, Bẹni-hádádì àti Hásáẹ́lì (7-15) Jèhórámù di ọba Júdà (16-24) Ahasáyà di ọba Júdà (25-29) 9 Wọ́n fòróró yan Jéhù ṣe ọba lórí Ísírẹ́lì (1-13) Jéhù pa Jèhórámù àti Ahasáyà (14-29) Wọ́n pa Jésíbẹ́lì; àwọn ajá jẹ ẹran ara rẹ̀ (30-37) 10 Jéhù pa agbo ilé Áhábù (1-17) Jèhónádábù dara pọ̀ mọ́ Jéhù (15-17) Jéhù pa àwọn olùjọ́sìn Báálì (18-27) Àkópọ̀ ìṣàkóso Jéhù (28-36) 11 Ataláyà fi ipá gba ìtẹ́ (1-3) Wọ́n fi Jèhóáṣì jọba ní bòókẹ́lẹ́ (4-12) Wọ́n pa Ataláyà (13-16) Àwọn àtúnṣe tí Jèhóádà ṣe (17-21) 12 Jèhóáṣì di ọba Júdà (1-3) Jèhóáṣì tún tẹ́ńpìlì ṣe (4-16) Àwọn ará Síríà gbógun wá (17, 18) Wọ́n pa Jèhóáṣì (19-21) 13 Jèhóáhásì di ọba Ísírẹ́lì (1-9) Jèhóáṣì di ọba Ísírẹ́lì (10-13) Èlíṣà dán ìtara Jèhóáṣì wò (14-19) Ikú Èlíṣà; egungun rẹ̀ jí ọkùnrin kan dìde (20, 21) Àsọtẹ́lẹ̀ tí Èlíṣà sọ kẹ́yìn ṣẹ (22-25) 14 Amasááyà di ọba Júdà (1-6) Ó bá Édómù àti Ísírẹ́lì jà (7-14) Ikú Jèhóáṣì ọba Ísírẹ́lì (15, 16) Ikú Amasááyà (17-22) Jèróbóámù Kejì di ọba Ísírẹ́lì (23-29) 15 Asaráyà di ọba Júdà (1-7) Àwọn ọba tó jẹ kẹ́yìn ní Ísírẹ́lì: Sekaráyà (8-12), Ṣálúmù (13-16), Ménáhémù (17-22), Pekaháyà (23-26), Pékà (27-31) Jótámù di ọba Júdà (32-38) 16 Áhásì di ọba Júdà (1-6) Áhásì fún àwọn ará Ásíríà ní àbẹ̀tẹ́lẹ̀ (7-9) Áhásì ṣe irú pẹpẹ àwọn abọ̀rìṣà (10-18) Ikú Áhásì (19, 20) 17 Hóṣéà di ọba Ísírẹ́lì (1-4) Wọ́n ṣẹ́gun Ísírẹ́lì (5, 6) Ísírẹ́lì lọ sí ìgbèkùn nítorí pé ó di apẹ̀yìndà (7-23) Wọ́n kó àwọn àjèjì wá sí àwọn ìlú Samáríà (24-26) Àwọn ará Samáríà ń ṣe oríṣiríṣi ẹ̀sìn (27-41) 18 Hẹsikáyà di ọba Júdà (1-8) Bí wọ́n ṣe ṣẹ́gun Ísírẹ́lì (9-12) Senakérúbù wá gbéjà ko Júdà (13-18) Rábúṣákè pẹ̀gàn Jèhófà (19-37) 19 Hẹsikáyà wá ìrànlọ́wọ́ Ọlọ́run lọ́dọ̀ Àìsáyà (1-7) Senakérúbù halẹ̀ mọ́ Jerúsálẹ́mù (8-13) Àdúrà Hẹsikáyà (14-19) Àìsáyà sọ ìdáhùn Ọlọ́run fún un (20-34) Áńgẹ́lì pa 185,000 àwọn ará Ásíríà (35-37) 20 Àìsàn Hẹsikáyà àti bí ara rẹ̀ ṣe yá (1-11) Àwọn òjíṣẹ́ láti Bábílónì (12-19) Ikú Hẹsikáyà (20, 21) 21 Mánásè di ọba Júdà; ó ta ẹ̀jẹ̀ sílẹ̀ (1-18) Wọ́n máa pa Jerúsálẹ́mù run (12-15) Ámọ́nì di ọba Júdà (19-26) 22 Jòsáyà di ọba Júdà (1, 2) Bí wọ́n ṣe máa tún tẹ́ńpìlì ṣe (3-7) Wọ́n rí ìwé Òfin (8-13) Húlídà sọ tẹ́lẹ̀ pé àjálù máa ṣẹlẹ̀ (14-20) 23 Àwọn àtúnṣe tí Jòsáyà ṣe (1-20) Wọ́n ṣe Ìrékọjá (21-23) Àwọn àtúnṣe míì tí Jòsáyà ṣe (24-27) Ikú Jòsáyà (28-30) Jèhóáhásì di ọba Júdà (31-33) Jèhóákímù di ọba Júdà (34-37) 24 Jèhóákímù ṣọ̀tẹ̀, ó sì kú (1-7) Jèhóákínì di ọba Júdà (8, 9) Ìgbà àkọ́kọ́ tí wọ́n kó wọn lọ sí Bábílónì (10-17) Sedekáyà di ọba Júdà; ó ṣọ̀tẹ̀ (18-20) 25 Nebukadinésárì dó ti Jerúsálẹ́mù (1-7) Ìparun Jerúsálẹ́mù àti tẹ́ńpìlì rẹ̀; wọ́n kó wọn lọ nígbà kejì (8-21) Wọ́n fi Gẹdaláyà ṣe gómìnà (22-24) Wọ́n pa Gẹdaláyà; àwọn èèyàn sá lọ sí Íjíbítì (25, 26) Wọ́n tú Jèhóákínì sílẹ̀ ní Bábílónì (27-30)