Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Ẹ́sírà Ẹ́SÍRÀ OHUN TÓ WÀ NÍNÚ ÌWÉ YÌÍ 1 Ọba Kírúsì pàṣẹ pé kí wọ́n tún tẹ́ńpìlì kọ́ (1-4) Ètò tí wọ́n ṣe kí àwọn tó wà nígbèkùn ní Bábílónì lè pa dà (5-11) 2 Orúkọ àwọn tó pa dà láti ìgbèkùn (1-67) Àwọn ìránṣẹ́ tẹ́ńpìlì (43-54) Àwọn ọmọ àwọn ìránṣẹ́ Sólómọ́nì (55-57) Àwọn ọrẹ àtinúwá fún tẹ́ńpìlì (68-70) 3 Wọ́n tún pẹpẹ kọ́, wọ́n sì rú àwọn ẹbọ (1-6) Wọ́n bẹ̀rẹ̀ sí í tún tẹ́ńpìlì kọ́ (7-9) Wọ́n fi ìpìlẹ̀ tẹ́ńpìlì lélẹ̀ (10-13) 4 Wọ́n gbógun ti iṣẹ́ títún tẹ́ńpìlì kọ́ (1-6) Àwọn ọ̀tá fi ìwé ẹ̀sùn ránṣẹ́ sí Ọba Atasásítà (7-16) Ìdáhùn Atasásítà (17-22) Iṣẹ́ kíkọ́ tẹ́ńpìlì dáwọ́ dúró (23-24) 5 Àwọn Júù pa dà sẹ́nu kíkọ́ tẹ́ńpìlì (1-5) Lẹ́tà tí Táténáì kọ sí Ọba Dáríúsì (6-17) 6 Àyẹ̀wò tí Dáríúsì ṣe àti àṣẹ tó pa (1-12) Wọ́n parí tẹ́ńpìlì, wọ́n sì ṣe ayẹyẹ ìṣílé (13-18) Wọ́n ṣe Ìrékọjá (19-22) 7 Ẹ́sírà wá sí Jerúsálẹ́mù (1-10) Lẹ́tà tí Atasásítà kọ sí Ẹ́sírà (11-26) Ẹ́sírà yin Jèhófà (27-28) 8 Orúkọ àwọn tó tẹ̀ lé Ẹ́sírà pa dà (1-14) Wọ́n múra ìrìn àjò náà (15-30) Wọ́n kúrò ní Bábílónì, wọ́n dé sí Jerúsálẹ́mù (31-36) 9 Àwọn ọmọ Ísírẹ́lì àti àwọn ọmọ ilẹ̀ míì ń fẹ́ ara wọn (1-4) Àdúrà ìjẹ́wọ́ ẹ̀ṣẹ̀ tí Ẹ́sírà gbà (5-15) 10 Wọ́n dá májẹ̀mú láti lé àwọn aya àjèjì lọ (1-14) Wọ́n lé àwọn aya àjèjì lọ (15-44)