Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Ẹ́sítà Ẹ́SÍTÀ OHUN TÓ WÀ NÍNÚ ÌWÉ YÌÍ 1 Ọba Ahasuérúsì se àsè ńlá ní Ṣúṣánì (1-9) Fáṣítì Ayaba kò ṣègbọràn (10-12) Ọba fọ̀rọ̀ lọ àwọn amòye rẹ̀ (13-20) Wọ́n fi àṣẹ ọba ránṣẹ́ (21, 22) 2 Wọ́n wá ayaba tuntun (1-14) Ẹ́sítà di ayaba (15-20) Módékáì tú àṣírí àwọn ọlọ̀tẹ̀ (21-23) 3 Ọba gbé Hámánì ga (1-4) Hámánì gbèrò láti pa àwọn Júù run (5-15) 4 Módékáì ṣọ̀fọ̀ (1-5) Módékáì ní kí Ẹ́sítà bá àwọn bẹ ọba (6-17) 5 Ẹ́sítà wá síwájú ọba (1-8) Hámánì ń bínú, ó sì ń gbéra ga (9-14) 6 Ọba dá Módékáì lọ́lá (1-14) 7 Ẹ́sítà tú Hámánì fó (1-6a) Wọ́n gbé Hámánì kọ́ sórí òpó igi tó ṣe (6b-10) 8 Ọba gbé Módékáì ga (1, 2) Ẹ́sítà bẹ ọba (3-6) Àṣẹ tí ọba fi ta ko àṣẹ àkọ́kọ́ (7-14) Àwọn Júù rí ìtura, wọ́n sì ń yọ̀ (15-17) 9 Àwọn Júù ṣẹ́gun (1-19) Wọ́n dá àjọyọ̀ Púrímù sílẹ̀ (20-32) 10 Módékáì di ẹni ńlá (1-3)