Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Jónà JÓNÀ OHUN TÓ WÀ NÍNÚ ÌWÉ YÌÍ 1 Jónà fẹ́ sá fún Jèhófà (1-3) Jèhófà mú kí ìjì kan tó lágbára jà (4-6) Jónà ló fa wàhálà tó dé bá wọn (7-13) Wọ́n ju Jónà sínú òkun tó ń ru gùdù (14-16) Ẹja ńlá kan gbé Jónà mì (17) 2 Àdúrà tí Jónà gbà látinú ẹja (1-9) Ẹja pọ Jónà sórí ilẹ̀ (10) 3 Jónà ṣègbọràn sí Ọlọ́run, ó sì lọ sí Nínéfè (1-4) Ọ̀rọ̀ Jónà mú kí àwọn ará Nínéfè ronú pìwà dà (5-9) Ọlọ́run pinnu pé òun ò ní pa Nínéfè run (10) 4 Jónà bínú, ó sì fẹ́ kú (1-3) Jèhófà kọ́ Jónà lẹ́kọ̀ọ́ pé kó jẹ́ aláàánú (4-11) “Ṣé ó yẹ kí inú bí ẹ tó báyìí?” (4) Jèhófà fi ewéko akèrègbè kọ́ Jónà lẹ́kọ̀ọ́ (6-10)