Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Kólósè KÓLÓSÈ OHUN TÓ WÀ NÍNÚ ÌWÉ YÌÍ 1 Ìkíni (1, 2) Pọ́ọ̀lù dúpẹ́ nítorí ìgbàgbọ́ àwọn ará Kólósè (3-8) Àdúrà pé kí wọ́n máa dàgbà sí i nípa tẹ̀mí (9-12) Ipa àrà ọ̀tọ̀ tí Kristi kó (13-23) Iṣẹ́ àṣekára tí Pọ́ọ̀lù ṣe fún ìjọ (24-29) 2 Kristi, àṣírí mímọ́ Ọlọ́run (1-5) Ẹ máa ṣọ́ra fún àwọn ẹlẹ́tàn (6-15) Ohun gidi náà ni Kristi (16-23) 3 Ìwà tuntun àti ìwà àtijọ́ (1-17) Ẹ sọ àwọn ẹ̀yà ara yín di òkú (5) Ìfẹ́ jẹ́ ìdè ìrẹ́pọ̀ pípé (14) Ìmọ̀ràn fún ìdílé Kristẹni (18-25) 4 Ìmọ̀ràn fún àwọn ọ̀gá (1) “Ẹ tẹra mọ́ àdúrà gbígbà” (2-4) Ẹ máa fi ọgbọ́n bá àwọn tó wà lóde lò (5, 6) Ìkíni tó fi parí ọ̀rọ̀ rẹ̀ (7-18)