Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun Ohun Tó Wà Nínú Ìwé 1 Tẹsalóníkà 1 TẸSALÓNÍKÀ OHUN TÓ WÀ NÍNÚ ÌWÉ YÌÍ 1 Ìkíni (1) Pọ́ọ̀lù dúpẹ́ nítorí ìgbàgbọ́ àwọn ará Tẹsalóníkà (2-10) 2 Iṣẹ́ òjíṣẹ́ Pọ́ọ̀lù ní Tẹsalóníkà (1-12) Àwọn ará Tẹsalóníkà gba ọ̀rọ̀ Ọlọ́run (13-16) Àárò àwọn ará Tẹsalóníkà ń sọ Pọ́ọ̀lù (17-20) 3 Ojú Pọ́ọ̀lù wà lọ́nà bó ṣe ń dúró ní Áténì (1-5) Ìròyìn tó ń tuni nínú tí Tímótì mú wá (6-10) Àdúrà fún àwọn ará Tẹsalóníkà (11-13) 4 Ìkìlọ̀ lórí ìṣekúṣe (1-8) Ẹ túbọ̀ nífẹ̀ẹ́ ara yín (9-12) “Ẹ má yọjú sí ọ̀rọ̀ ọlọ́rọ̀” (11) Àwọn tó kú nínú Kristi ló máa kọ́kọ́ dìde (13-18) 5 Ọjọ́ Jèhófà ń bọ̀ (1-5) “Àlàáfíà àti ààbò!” (3) Ẹ wà lójúfò, ẹ máa ronú bó ṣe tọ́ (6-11) Ọ̀rọ̀ ìyànjú (12-24) Ìkíni tó fi parí ọ̀rọ̀ rẹ̀ (25-28)