Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun Ohun Tó Wà Nínú Ìwé 2 Pétérù 2 PÉTÉRÙ OHUN TÓ WÀ NÍNÚ ÌWÉ YÌÍ 1 Ìkíni (1) Ẹ jẹ́ kí pípè yín dá yín lójú (2-15) Àwọn ànímọ́ tí a fi kún ìgbàgbọ́ (5-9) Ọ̀rọ̀ àsọtẹ́lẹ̀ tí a mú kó túbọ̀ dá wa lójú (16-21) 2 Àwọn olùkọ́ èké máa wá (1-3) Ìdájọ́ àwọn olùkọ́ èké kò ní yẹ̀ (4-10a) Ọlọ́run ju àwọn áńgẹ́lì sínú Tátárọ́sì (4) Ìkún Omi; Sódómù àti Gòmórà (5-7) Bí a ṣe lè dá àwọn olùkọ́ èké mọ̀ (10b-22) 3 Àwọn tó ń fini ṣẹlẹ́yà kò ka ìparun tó ń bọ̀ sí (1-7) Jèhófà kì í fi nǹkan falẹ̀ (8-10) Ẹ ronú nípa irú ẹni tó yẹ kí ẹ jẹ́ (11-16) Ọ̀run tuntun àti ayé tuntun (13) Ẹ ṣọ́ra kí wọ́n má bàa ṣì yín lọ́nà (17, 18)