Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun Ohun Tó Wà Nínú Ìwé 3 Jòhánù 3 JÒHÁNÙ OHUN TÓ WÀ NÍNÚ ÌWÉ YÌÍ Ìkíni àti àdúrà (1-4) Jòhánù gbóríyìn fún Gáyọ́sì (5-8) Díótíréfè fẹ́ fi ara rẹ̀ ṣe olórí (9, 10) Àwọn ará ròyìn Dímẹ́tíríù dáadáa (11, 12) Ìbẹ̀wò tó fẹ́ ṣe àti ìkíni (13, 14)