Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Rúùtù RÚÙTÙ OHUN TÓ WÀ NÍNÚ ÌWÉ YÌÍ 1 Élímélékì àti ìdílé rẹ̀ kó lọ sí Móábù (1, 2) Náómì, Ọ́pà àti Rúùtù di opó (3-6) Rúùtù kò fi Náómì àti Jèhófà sílẹ̀ (7-17) Náómì pa dà sí Bẹ́tílẹ́hẹ́mù, Rúùtù tẹ̀ lé e (18-22) 2 Rúùtù pèéṣẹ́ ní oko Bóásì (1-3) Rúùtù àti Bóásì pàdé (4-16) Rúùtù sọ fún Náómì bí Bóásì ṣe ṣojúure sí òun (17-23) 3 Náómì sọ ohun tí Rúùtù máa ṣe (1-4) Rúùtù àti Bóásì ní ibi ìpakà (5-15) Rúùtù pa dà sọ́dọ̀ Náómì (16-18) 4 Bóásì tún ìdílé Élímélékì rà (1-12) Rúùtù bí Óbédì fún Bóásì (13-17) Ìran Dáfídì (18-22)