1 SÁMÚẸ́LÌ
OHUN TÓ WÀ NÍNÚ ÌWÉ YÌÍ
-
Ọlọ́run pe Sámúẹ́lì, ó sì sọ ọ́ di wòlíì (1-21)
-
Àwọn Filísínì dá Àpótí náà pa dà sí Ísírẹ́lì (1-21)
-
Sámúẹ́lì pàdé Sọ́ọ̀lù (1-27)
-
Bí Jónátánì ṣe jẹ́ olóòótọ́ sí Dáfídì (1-42)
-
Àwọn Filísínì fún Dáfídì ní Síkílágì (1-12)
-
Sọ́ọ̀lù lọ bá abẹ́mìílò ní Ẹ́ń-dórì (1-25)
-
Àwọn Filísínì kò fọkàn tán Dáfídì (1-11)
-
Ikú Sọ́ọ̀lù àti ti àwọn ọmọ rẹ̀ mẹ́ta (1-13)