JEREMÁYÀ
OHUN TÓ WÀ NÍNÚ ÌWÉ YÌÍ
-  1  - 
- Ọlọ́run yan Jeremáyà láti jẹ́ wòlíì (1-10) 
- Ìran nípa igi álímọ́ńdì (11, 12) 
- Ìran nípa ìkòkò ìsebẹ̀ (13-16) 
- Ọlọ́run fún Jeremáyà lágbára kó lè jẹ́ iṣẹ́ tó rán an (17-19) 
 
-  2  
-  3  - 
- Bí ìpẹ̀yìndà Ísírẹ́lì ṣe burú tó (1-5) 
- Ísírẹ́lì àti Júdà jẹ̀bi àgbèrè (6-11) 
- Ọlọ́run ní kí wọ́n ronú pìwà dà (12-25) 
 
-  4  - 
- Ìrònúpìwàdà ń mú ìbùkún wá (1-4) 
- Àjálù yóò wá láti àríwá (5-18) 
- Àjálù tó ń bọ̀ kó ẹ̀dùn ọkàn bá Jeremáyà (19-31) 
 
-  5  - 
- Àwọn èèyàn náà kò gba ìbáwí Jèhófà (1-13) 
- Ìparun ń bọ̀, àmọ́ kì í ṣe ìparun pátápátá (14-19) 
- Jèhófà pe àwọn èèyàn náà wá jíhìn (20-31) 
 
-  6  - 
- Ọ̀tá máa tó dó ti Jerúsálẹ́mù (1-9) 
- Ìbínú Jèhófà lórí Jerúsálẹ́mù (10-21) 
- Ọ̀tá ya wọ ilẹ̀ náà láti àríwá (22-26) 
- Jeremáyà máa di ẹni tó ń yọ́ wúrà àti fàdákà mọ́ (27-30) 
 
-  7  - 
- Ìgbẹ́kẹ̀lé asán nípa tẹ́ńpìlì Jèhófà (1-11) 
- Tẹ́ńpìlì náà yóò dà bíi Ṣílò (12-15) 
- Ọlọ́run kọ ìjọsìn wọn (16-34) 
 
-  8  - 
- Àwọn èèyàn náà ń ṣe ohun tí ọ̀pọ̀ èèyàn ń ṣe (1-7) 
- Ǹjẹ́ ọgbọ́n lè wà láìsí ọ̀rọ̀ Jèhófà? (8-17) 
- Jeremáyà kédàárò lórí ìṣubú Júdà (18-22) 
 
-  9  - 
- Ìbànújẹ́ Jeremáyà pọ̀ gan-an (1-3a) 
- Jèhófà pe Júdà wá jíhìn (3b-16) 
- Ìdárò lórí Júdà (17-22) 
- Máa yangàn torí pé o mọ Jèhófà (23-26) 
 
- 10  - 
- Àwọn ọlọ́run orílẹ̀-èdè àti Ọlọ́run alààyè (1-16) 
- Ìparun àti ìgbèkùn ń bọ̀ lọ́nà (17, 18) 
- Inú Jeremáyà bà jẹ́ (19-22) 
- Àdúrà tí wòlíì náà gbà (23-25) 
 
- 11  - 
- Júdà da májẹ̀mú Ọlọ́run (1-17) 
- Jeremáyà dà bí ọ̀dọ́ àgùntàn tí wọ́n fẹ́ lọ pa (18-20) 
- Àtakò tí àwọn ará ìlú Jeremáyà ṣe (21-23) 
 
- 12  
- 13  - 
- Àmùrè aṣọ ọ̀gbọ̀ tó bà jẹ́ (1-11) 
- Ọlọ́run máa fọ́ àwọn ìṣà wáìnì (12-14) 
- Júdà alágídí máa lọ sí ìgbèkùn (15-27) 
 
- 14  - 
- Ọ̀dá, ìyàn àti idà (1-12) 
- Ọlọ́run dá àwọn wòlíì èké lẹ́bi (13-18) 
- Jeremáyà sọ ẹ̀ṣẹ̀ tí àwọn èèyàn náà dá (19-22) 
 
- 15  - 
- Jèhófà kò ní yí ìdájọ́ rẹ̀ pa dà (1-9) 
- Jeremáyà mú ẹjọ́ rẹ̀ wá (10) 
- Ohun tí Jèhófà sọ (11-14) 
- Àdúrà Jeremáyà (15-18) 
- Jèhófà fún Jeremáyà lágbára (19-21) 
 
- 16  - 
- Jeremáyà kò gbọ́dọ̀ gbéyàwó tàbí kó ṣọ̀fọ̀, kò sì gbọ́dọ̀ jẹ àsè (1-9) 
- Ìjìyà, lẹ́yìn náà ìpadàbọ̀sípò (10-21) 
 
- 17  - 
- Júdà ti jingíri sínú ẹ̀ṣẹ̀ (1-4) 
- Ìbùkún tó wà nínú gbígbẹ́kẹ̀lé Jèhófà (5-8) 
- Ọkàn tó ń tanni jẹ (9-11) 
- Jèhófà jẹ́ ìrètí Ísírẹ́lì (12, 13) 
- Àdúrà Jeremáyà (14-18) 
- Jẹ́ kí Sábáàtì wà ní mímọ́ (19-27) 
 
- 18  - 
- Amọ̀ tó wà lọ́wọ́ amọ̀kòkò (1-12) 
- Jèhófà kẹ̀yìn sí Ísírẹ́lì (13-17) 
- Wọ́n gbìmọ̀ ibi sí Jeremáyà; ó ké pe Ọlọ́run (18-23) 
 
- 19  
- 20  
- 21  
- 22  
- 23  - 
- Àwọn olùṣọ́ àgùntàn rere àti búburú (1-4) 
- Ààbò lábẹ́ “èéhù kan tí ó jẹ́ olódodo” (5-8) 
- Ọlọ́run dá àwọn wòlíì èké lẹ́bi (9-32) 
- “Ẹrù tó wúwo” látọ̀dọ̀ Jèhófà (33-40) 
 
- 24  
- 25  
- 26  
- 27  
- 28  
- 29  
- 30  
- 31  
- 32  
- 33  - 
- Ìlérí ìpadàbọ̀sípò (1-13) 
- Ààbò lábẹ́ “èéhù òdodo” (14-16) 
- Májẹ̀mú tí Ọlọ́run bá Dáfídì àti àwọn àlùfáà dá (17-26) 
 
- 34  
- 35  
- 36  - 
- Jeremáyà ń sọ ohun tí wọ́n ń kọ sínú àkájọ ìwé (1-7) 
- Bárúkù ka ọ̀rọ̀ inú àkájọ ìwé sókè (8-19) 
- Jèhóákímù dáná sun àkájọ ìwé náà (20-26) 
- A tún ọ̀rọ̀ náà kọ sínú àkájọ ìwé tuntun (27-32) 
 
- 37  - 
- Àwọn ará Kálídíà ṣígun lọ fúngbà díẹ̀ (1-10) 
- Wọ́n fi Jeremáyà sẹ́wọ̀n (11-16) 
- Sedekáyà pàdé Jeremáyà (17-21) 
 
- 38  - 
- Wọ́n ju Jeremáyà sínú kòtò omi (1-6) 
- Ebedi-mélékì gba Jeremáyà sílẹ̀ (7-13) 
- Jeremáyà rọ Sedekáyà pé kó juwọ́ sílẹ̀ (14-28) 
 
- 39  
- 40  - 
- Nebusarádánì jẹ́ kí Jeremáyà lọ ní òmìnira (1-6) 
- A yan Gẹdaláyà ṣe olórí ilẹ̀ náà (7-12) 
- Wọ́n dìtẹ̀ Gẹdaláyà (13-16) 
 
- 41  
- 42  
- 43  
- 44  
- 45  
- 46  
- 47  
- 48  
- 49  - 
- Àsọtẹ́lẹ̀ lórí àwọn ọmọ Ámónì (1-6) 
- Àsọtẹ́lẹ̀ lórí Édómù (7-22) 
- Àsọtẹ́lẹ̀ lórí Damásíkù (23-27) 
- Àsọtẹ́lẹ̀ lórí Kédárì àti Hásórì (28-33) 
- Àsọtẹ́lẹ̀ lórí Élámù (34-39) 
 
- 50  
- 51  
- 52  - 
- Sedekáyà ṣọ̀tẹ̀ sí Bábílónì (1-3) 
- Nebukadinésárì dó ti Jerúsálẹ́mù (4-11) 
- Ìparun Jerúsálẹ́mù àti tẹ́ńpìlì rẹ̀ (12-23) 
- Wọ́n kó àwọn èèyàn lọ sí ìgbèkùn ní Bábílónì (24-30) 
- Wọ́n dá Jèhóákínì sílẹ̀ lẹ́wọ̀n (31-34)