Alẹ́ Ọjọ́ Ìrántí
A KÉ SÍ Ọ
ÌṢE ÌRÁNTÍ IKÚ JESU KRISTI LỌ́DỌỌDÚN
TUESDAY, APRIL 2, 1996
GBỌ̀NGÀN ÌJỌBA ÀWỌN ẸLẸ́RÌÍ JEHOFA
Jesu fúnra rẹ̀ fi ìṣe ìrántí ikú rẹ̀ lélẹ̀ ní alẹ́ ọjọ́ tí ó ṣáájú ikú rẹ̀. Ó jẹ́ ayẹyẹ kan tí ó rọrùn. Àwọn Ẹlẹ́rìí Jehofa ké sí ọ láti dara pọ̀ mọ́ wọn láti pa ìṣẹ̀lẹ̀ pàtàkì yìí mọ́ ní Gbọ̀ngàn Ìjọba tí ó sún mọ́ ibùgbé rẹ jù lọ. Wádìí lọ́wọ́ àwọn Ẹlẹ́rìí Jehofa ládùúgbò rẹ nípa àkókò àti ibi pàtó tí a óò ti ṣe ìpàdé náà.