Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
May 8, 2001
Ṣé Àwọn Ẹlẹ́wọ̀n Lè Yí Padà?
Lọ́pọ̀ ìgbà, ọgbà ẹ̀wọ̀n wulẹ̀ jẹ́ ibi tí wọ́n ti ń kọ́ láti hùwà ọ̀daràn tó túbọ̀ rinlẹ̀ sí i. Àmọ́, kà nípa bí a ṣe ran àwọn ẹlẹ́wọ̀n kan lọ́wọ́ láti ṣe ojúlówó àyípadà.
3 Ìṣòro Dé Bá Àwọn Ọgbà Ẹ̀wọ̀n
4 Àbí Ohun Táa Pè Lójútùú Ló Ń Dá Kún Ìṣòro?
8 Ṣé ó Ṣeé Ṣe—Lóòótọ́ Láti Yí Àwọn Ọ̀daràn Padà?
12 Ìsìn Tí Ilẹ̀ Soviet Dojú Àtakò Kọ
21 Kí Ló Ń dúró De Ìsìn Lọ́jọ́ Iwájú?
27 Wọ́n Ń Lo Abala “Wíwo Ayé” Ní Ilé Ẹ̀kọ́
30 Ìpakúpa Rẹpẹtẹ Tó Wáyé Nígbà Ìjọba Násì Ṣé Ó Ṣì Tún Lè Ṣẹlẹ̀?
32 ‘Ó Ń kọ́ni Lẹ́kọ̀ọ́, Ó Ń pèsè Ìsọfúnni’
Èé Ṣe Tó Fi Yẹ Kí N Sún Mọ́ Àwọn Òbí Mi Àgbà? 24
Wọ́n sábàá máa ń pa àwọn obí àgbà tì. Ìdí wo ló fi ṣe pàtàkì pé kí á kà wọ́n sí?
Ṣé Ọlọ́run Ẹ̀yà Júù Ni Jèhófà? 28
Báwo la ṣe mọ̀ pé Ọlọ́run èèyàn gbogbo orílẹ̀-èdè ni Jèhófà jẹ́?