Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
November 8, 2002
Ǹjẹ́ Àrùn Éèdì Tó Ń Pa Àwọn Èèyàn Nípakúpa Yìí Máa Dópin?
Ajàkáyé ni àrùn éèdì. Àmọ́, Gúúsù Áfíríkà ló ń bá fínra jù lọ ní lọ́wọ́lọ́wọ́. Ǹjẹ́ ojútùú kan wà fún un?
3 “Àjàkálẹ̀ Àrùn Tó Burú Jù Lọ Táráyé Ò Rírú Ẹ̀ Rí”
4 Àrùn Éèdì Gba Ilẹ̀ Áfíríkà Kan
8 Ṣé Àrùn Éèdì Máa Dópin? Bó Bá Rí Bẹ́ẹ̀, Lọ́nà Wo?
17 Ṣé Kì Í Ṣe Pé Pàbó ni Gbogbo Ìrètí Àlàáfíà Ń Já Sí?
18 Àwọn Ẹlẹ́sìn Tìtorí Àlàáfíà Pé Jọ sí Ìlú Assisi
22 Ta Ló Máa Mú Àlàáfíà Pípẹ́títí Wá?
24 Nígbà Tí Àṣìṣe Tí Kò Tó Nǹkan Bá Di Àjálù Ńlá
25 Èmi Ògbóǹkangí Olóṣèlú Tẹ́lẹ̀ Di Kristẹni Tí Kò Dá Sí Ìṣèlú Mọ́
30 Wíwo Ayé
32 Àwọn ìdáhùn tó gbéṣẹ́ rèé sí àwọn ìbéèrè tó o ti ń béèrè!
Ǹjẹ́ Ọlọ́run Á Gbójú Fo Àwọn Kùdìẹ̀-Kudiẹ Wa? 12
Ṣé a lè borí àwọn kùdìẹ̀-kudiẹ wa? Kí la gbọ́dọ̀ ṣe?
Ǹjẹ́ Mo Nílò Tẹlifóònù Alágbèérìn? 14
Tẹlifóònù mọ́ńbé yìí ní àwọn àléébù kan. Ọ̀nà wo la lè gbà lò ó tí kò ní dọ̀gá lé wa lórí?
[Àwọn àwòrán Credit Line tó wà ní ojú ìwé 2]
Copyright Sean Sprague/Panos Pictures
Fọ́tò AP/Efrem Lukatsky
Ẹ̀YÌN ÌWÉ: Alyx Kellington/Index Stock Photography