Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
January-March 2007
Ìgbà Kan Ń Bọ̀ Tí Àìsàn Ò Ní Sí Mọ́!
Èyí tí ìmọ̀ ìjìnlẹ̀ ti gbé ṣe nínú ọ̀ràn ìṣègùn àti ìtọ́jú ara ní í jóhun. Síbẹ̀, àìsàn ò tíì yé fìtínà aráyé. Ǹjẹ́ ìgbà kan tiẹ̀ ń bọ̀ tí àìsàn ò ní sí mọ́?
4 Ṣé Ìmọ̀ Sáyẹ́ǹsì Á Gba Aráyé Lọ́wọ́ Àìsàn?
10 Ìgbà Kan Ń Bọ̀ Tí Àìsàn Ò Ní Sí Mọ́!
28 “Àkókò Oúnjẹ Máa Ń Mú Ká Túbọ̀ Sún Mọ́ra”
29 Mo Ti Fìgbà Kan Rí Dà bí Ọmọ Onínàákúnàá
32 “Ó Kàmàmà”
Ìgbà Wo Ló Yẹ Kí N Bẹ̀rẹ̀ sí Í Bá Ẹni Tí Kì Í Ṣe Ọkùnrin Tàbí Obìnrin Bíi Tèmi Jáde?
Ṣé Bí Ìfẹ́ Bá Ti Wà, Kò Sóhun Tó Burú Nínú Ìbálòpọ̀ Ṣáájú Ìgbéyàwó?