Ṣé Bíbélì Lè Mú Káyé Ẹ Dáa Sí I?
No. 3 2019
© 2019 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
Ìtẹ̀jáde yìí kì í ṣe títà. Ó jẹ́ ara iṣẹ́ ìkọ́nilẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì kárí ayé tá à ń fi ọrẹ àtinúwá tì lẹ́yìn. Tó o bá fẹ́ ṣètọrẹ, jọ̀wọ́ lọ sí ìkànnì wa donate.jw.org. Bá ò bá fi hàn pé ó yàtọ̀, inú Bíbélì Mímọ́ Ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun la ti mú gbogbo ẹsẹ Ìwé Mímọ́ tá a lò.