Nǹkan Ń Gbówó Lórí! Ọgbọ́n Wo Lo Lè Dá Sí I?
© 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
A kì í ta ìwé yìí. Ó wà lára ohun tá a fi ń kọ́ àwọn èèyàn lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì kárí ayé. Owó táwọn èèyàn fi ń ṣètìlẹ́yìn la fi ń ṣe gbogbo ohun tá à ń ṣe. Tó o bá fẹ́ ṣètìlẹ́yìn, jọ̀wọ́ lọ sí ìkànnì donate.jw.org. Inú Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun la ti mú gbogbo ẹsẹ Bíbélì tá a lò, àfi tá a bá sọ pé Bíbélì míì la lò.