Ọ̀rọ̀ Ìṣáájú
Awọn eniyan maa nsọ niye igba pe wọn nígbàgbọ́ ninu Mẹtalọkan, síbẹ̀ òye wọn nipa rẹ̀ yatọ.
Ki ni Mẹtalọkan naa jẹ́, níti gidi?
Bibeli ha fi kọ́ni bi?
Jesu Kristi ha ni Ọlọrun Olodumare tí ó sì jẹ́ apakan Mẹtalọkan naa bi?
Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.
Má bínú, fídíò yìí kò jáde.