Ojú Ìwé Tí Wọ́n Kọ Àkọlé Sí/Ojú Ìwé Tí Wọ́n Kọ Orúkọ Òǹṣèwé sí
Ọkunrin Titobilọla Julọ Ti O Tii Gbé Ayé Rí
A Tẹ Èyí ní Ọdún 2006
A tẹ ìwé yìí jáde gẹ́gẹ́ bí ara iṣẹ́ ìkọ́nilẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì kárí ayé tí à ń fi ọrẹ àtinúwá ṣètìlẹ́yìn fún.
Awọn ẹsẹ Bibeli tí a fayọ ninu iwe yii jẹ lati inu awọn itumọ Bibeli ti èdè Yoruba, ayafi bi a bá fihan pe ominira ni. Nibi ti a bá ti fi NW hàn tẹle ẹsẹ Bibeli kan tí a fayọ, o nfihan pe a ti tumọ ẹsẹ naa lati inu Bibeli èdè Gẹẹsi, itumọ ode-oni ti New World Translation of the Holy Scriptures, itẹjade ti 1984
Orisun Aworan
Aworan ilẹ́ ti o ṣaaju Akori 1: a gbé e ka ori aworan ilẹ kan lati ọwọ Pictorial Archive (Near Eastern History) Est. and Survey of Israel