Ojú Ìwé Tí Wọ́n Kọ Àkọlé Sí/Ojú Ìwé Tí Wọ́n Kọ Orúkọ Òǹṣèwé sí
Ki Ni Ète Igbesi-Aye? Bawo Ni Iwọ Ṣe Le Rí I?
A Tún Un Tẹ̀ ní Ọdún 2009
A tẹ ìwé yìí jáde gẹ́gẹ́ bí ara iṣẹ́ ìkọ́nilẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì kárí ayé tí à ń fi ọrẹ àtinúwá ṣètìlẹ́yìn fún.
Ayafi bi a bá fihàn pe omiran ni, awọn ẹsẹ Ìwé Mímọ́ ti a fayọ ninu ìwé yii jẹ lati inu Bibeli Mímọ́ ni èdè Yoruba, itẹjade ti 1960, ni àkọtọ́ ti ode-oni. Nibi ti a bá ti fi NW hàn tẹ̀lé ẹsẹ Bibeli kan ti a fayọ, o fihàn pe a ṣe itumọ naa lati inu Bibeli èdè Gẹẹsi òde-òní ti New World Translation of the Holy Scriptures—With References, Itẹjade ti 1984.