Ojú Ìwé Tí Wọ́n Kọ Àkọlé Sí/Ojú Ìwé Tí Wọ́n Kọ Orúkọ Òǹṣèwé sí
Ìmọ̀ Tí Ń Sinni Lọ sí Ìyè Àìnípẹ̀kun
A Tẹ̀ Ẹ́ ní Ọdún 2006
A tẹ ìwé yìí jáde gẹ́gẹ́ bí ara iṣẹ́ ìkọ́nilẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì kárí ayé tí à ń fi ọrẹ àtinúwá ṣètìlẹ́yìn fún.
Gbogbo àwọn ẹsẹ̀ ìwé mímọ́ wá láti inú Bibeli Mimọ ní èdè yoruba, ìtẹ̀jáde ti 1960, ní àkọtọ́ ti òde-òní, àyàfi àwọn tí a fàyọ láti inú ìwé mímọ́ lédè griki ni ó wá láti inú Ìwé Mímọ́ Kristian Lédè Griki ní Ìtumọ̀ Ayé Titun. Níbi tí a bá ti fi NW hàn tẹ̀lé ẹsẹ̀ tí a fàyọ, ó fi hàn pé a lo New World Translation of the Holy Scriptures—With References, Ìtẹ̀jáde ti 1984.
Orísun Àwòrán
Ojú-ìwé 20, Ẹ̀yìn Ìwé: Bibelmuseum, Münster
Ojú-ìwé 100, Ìfebipani: Mark Peters/Sipa Press; Sójà: Bill Gentile/Sipa Press; Àwọn Ọkọ̀ Ogun Ojú Òfúúrufú: Fọ́tò USAF
Ojú-ìwé 101, Ìbàyíkájẹ́: Fọ́tò WHO Láti Ọwọ́ P. Almasy; Àwọn Ènìyàn Ojú Pópó: Alexandre Tokitaka/Sipa Press