Ojú Ìwé Tí Wọ́n Kọ Àkọlé Sí/Ojú Ìwé Tí Wọ́n Kọ Orúkọ Òǹṣèwé sí
Kí Ni Ọlọrun Ń Béèrè Lọ́wọ́ Wa?
A Tún Un Tẹ̀ ní Ọdún 2006
A tẹ ìwé yìí jáde gẹ́gẹ́ bí ara iṣẹ́ ìkọ́nilẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì kárí ayé tí à ń fi ọrẹ àtinúwá ṣètìlẹ́yìn fún.
Gbogbo àwọn ẹsẹ Ìwé Mímọ́ wá láti inú Bibeli Mimọ ní èdè Yoruba, ìtẹ̀jáde ti 1960, ní àkọtọ́ òde òní, àyàfi àwọn tí a fà yọ láti inú Ìwé Mímọ́ Lédè Gíríìkì ni ó wá láti inú Ìwé Mímọ́ Kristian Lédè Griki ní Ìtumọ̀ Ayé Titun. Níbi tí a bá ti fi NW hàn tẹ̀ lé ẹsẹ tí a fà yọ, ó fi hàn pé a lo New World Translation of the Holy Scriptures—With References